Rasak Malik

Ní Ayé Mìíràn

by

Ní ayé mìíràn mo fẹ́ jẹ́ bàbá láì fojú sunkún àwọn ọmọ mi, láì ní ìrírí ètùtù wíwo àwọn ọmọ mi padà sílé bíi ara tí wọ́n kákò bíi ẹní-ìkírun, láì lo awọn alẹ́ mi pẹ̀lú wọn láti máa sọ ìtàn ìlú tí onílé ti ń di àjòjì tí wọ́n ń wá ibùgbé. Mo fẹ́ […]