Translation

Ìjẹ́wọ́ Ìnàkí Shìnágawà Kan

by

Láti Ọwọ́ Haruki Murakami (New Yorker (© June 2020) Tí Kọ́lá Túbọ̀sún túmọ̀ Mo pàdé alàgbà ìnàkí yìí nílé ìtura Japaní kan nínú ilé-ìwẹ̀ onísun-gbígbóná kan ní Ìjọba Ìbílẹ̀ Gunmà, ní bíi ọdún márùún sẹ́yìn. Ilé ìtura náà ti gbó, tàbí ká ní ó ti ń d’àlàpà. Kò fẹ́ẹ̀ lè dá dúró, mo kàn ní […]